< Return to Video

Earth in 100 Seconds - Preview for Translation Captioning (Password: AreYouReady)

  • 0:05 - 0:07
    Kí ni à ń lo ayé fún?
  • 0:07 - 0:09
    Ẹ jẹ́ ká rin láti wádìí.
  • 0:10 - 0:12
    Àáyá kọ̀ọ̀kan ìrìn wa ṣàfihàn 1%
    ilẹ̀.
  • 0:12 - 0:13
    Àti lílò rẹ̀.
  • 0:14 - 0:16
    Ayé ní ìṣéjú-àáyá 100.
  • 0:17 - 0:17
    Ṣé o ṣetán?
  • 0:22 - 0:26
    A lo bí ìṣẹ́jú-àáyá 10 àkọ́kọ́ láti
    rìn káàkiri ilẹ̀ yìnyín tó tutù kan.
  • 0:32 - 0:36
    Àti 11 tó kàn ní ìyàngbẹ ilẹ̀,
    aṣálẹ̀ àti àwọn ilẹ̀ àpáta.
  • 0:44 - 0:44
    Kàn síwájú.
  • 0:44 - 0:47
    Ìṣéjú-àáyá 2 ìrìn wa jẹ́
    líla agbájọ abẹ̀mí kọjá.
  • 0:47 - 0:48
    tí ó kéré jù tí à ń lò,
  • 0:49 - 0:49
    pẹ̀lú nìkan
  • 0:49 - 0:51
    àáyá 8 t`àwọn igbó tí ò bàjẹ́.
  • 0:53 - 0:57
    Gbogbo ilẹ̀ yòókù ni
    àwọn ènìyàn ń lò dáadáa tààrà.
  • 0:58 - 1:00
    1% ilẹ̀ ni wọ́n kọ́ ilé sórí ẹ̀,
  • 1:00 - 1:03
    ṣùgbọ́n àmì ẹsẹ̀ wa gbilẹ̀
    jákèjádò ayé.
  • 1:03 - 1:06
    Àwọn irúgbìn bo 11% ilẹ̀,
  • 1:06 - 1:09
    ó fẹ́rẹ̀ẹ́ tó ìdajì ni wọ́n ń
    fún ẹran ọ̀sìn jẹ.
  • 1:09 - 1:10
    tàbí fún àáyá 8
  • 1:11 - 1:12
    a wà nínú igbó.
  • 1:13 - 1:14
    A ṣètò àwọn igbó yìí fún gẹdú.
  • 1:15 - 1:17
    Tó sì kópa
    nínú ìṣàkóso ojú-ọjọ́ wa,
  • 1:17 - 1:19
    afẹ́fẹ́ àti omi.
  • 1:19 - 1:21
    Fún ìmọ̀,
    àwọn kan dára fún ẹranko,
  • 1:22 - 1:24
    ṣùgbọ́n ó bani nínú jẹ́ láti rí i pé
    a ti fi
  • 1:24 - 1:27
    Ó ju ìdá kan nínú mẹ́ta ilẹ̀
    fún pípèsè ẹran, wàrà àti ẹranko.
  • 1:29 - 1:31
    A kò fi bẹ́ẹ̀ lo
    ìṣẹ́jú-àáyá 14 ìrìn wa,
  • 1:31 - 1:33
    Àwọn koríko igbó àti agbègbè,
  • 1:33 - 1:34
    pẹ̀lú
  • 1:34 - 1:35
    àwọn màlúù àgùntàn àti ewúrẹ́.
  • 1:35 - 1:37
    Àwọn ẹranko igbó le jẹko níbí.
  • 1:37 - 1:41
    A máa ń tọ́jú àwọn ẹran ọ̀sìn kan dáadáa
    kí àwọn ẹ̀yà mìíràn le dára.
  • 1:41 - 1:44
    Púpọ̀ kìí ṣe ìṣẹ́jú-àáyá
    19 tó kẹ́yìn wa,
  • 1:44 - 1:46
    pẹ̀lú oko mẹ́ta tí a sábà ń
    lò láti sin àwọn
  • 1:46 - 1:47
    màlúù.
  • 1:51 - 1:53
    Àwọn màlúù ni olúwa àpapọ̀
  • 1:53 - 1:55
    tó fẹ́rẹ̀ẹ́ ga ju ìgbà 10
  • 1:55 - 1:57
    gbogbo àwọn ẹranko
    igbó lọ papọ̀.
  • 1:59 - 2:01
    Ní àsìkò àjálù ojú-ọjọ́
  • 2:01 - 2:03
    tí ọ̀kẹ́ àìmọye ẹ̀yà bá
    sì wà nínú ewu ìparun,
  • 2:04 - 2:04
    kí nìdí
  • 2:04 - 2:07
    akò ṣe ṣàgbéyẹ̀wò ìdàpọ̀ àwọn ilẹ̀ wa àti ìlò wọ́n?
  • 2:08 - 2:09
    Mo nílò igi síi, jọ̀wọ́.
  • 2:10 - 2:11
    Mo rò pé àdánidá tó
    pọ̀si yóò dára.
  • 2:12 - 2:15
    Ìbá ṣe dára tó bi a bá pèsè ààyè
    si fún àdánidá?
Title:
Earth in 100 Seconds - Preview for Translation Captioning (Password: AreYouReady)
Description:

more » « less
Video Language:
English
Duration:
02:19

Yoruba subtitles

Revisions